A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON COMPOUND NI ILU ORA-IGBOMINA

Bí ọmọdé ô bá ìtàn, á bá àrọ́bá - itan nipa awon eyan, ibi ati oun meremere ti o jo mo Yoruba/About the history of the people, places and every other Yoruba related things.
Post Reply
Agboola gbenga
Reactions:
Posts: 31
Joined: Thu Sep 08, 2016 9:51 am
Gender: Male

ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON COMPOUND NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by Agboola gbenga » Mon Jan 09, 2017 2:31 pm

Awa lomo olotoro elere, omo elerin nla funfun, koto
ajija mekun lepe, keba Mi mekun lepe, keba Mi
mu ewure ibe, ewure otoro bami leru ju ekun ibe lo,
awa lomo jamo niya sonu, awa lomo jawe lemo lori, awa lomo ogoro nbe
nile e si aha, omo ogbon ni muni sahun nitori ba
meji ko, nitori awon wobia ni, omo asu olele
nigbati e si eree, awa lomo o gbo kuku ojo da omi agbada nu
lore, ojo setan e tun ro mo, gbogbo aya-oba ile Wa lo
KO omo le itan, omo oniwo ku loyegbe kanran bi oko tuntun, ojo pa oniru iwo, ko se yan mo. ojo pa oniyo iwo, iyo di okuta. ojo pa elekuru iwo, ko se yan mo. lope pekun, leti awoji, moriwo
Sara ogun ti iyemi kanle lepe, omo koro-awo ajiki, omo koro-awo ajige. awa lomo Alaka
balagba, omo awobi sakaro Loko, Omo arowora lotoro. Awa lomo eniwo
ye yiwo, awa lomo ejemu yoo ni Ora, omo ejemu
abeki, omo ejemu owojemiosimi, awa lomo Ada
olufe, omo sajiku oro obalufon, Omo obalufe ni Ife ooye,Omo Seriki Ologun dudu, Omo a keru weeere soko, Omo a fun ni lowo nigba to Soro, Eerun ni o je ki n musu loke Ogba dele, Omo Aworo ti kii seke, Baba wa lo nile dajumonmu, Omo Koro Awo ajiki, Omo a lu koko soro, Omo ipako o gbo suti Ori elegan ni o fe pe, Iran baba wa kii je efo odu
Nitori iran omo aniwo ni. omo olodo kan otororooo, omo olodo kan
otararaaa, omo olodokan odo kan to san lo si eyinkule oshin to di abata, omo onife abure, omo amagbada owo remo, omo ooni erujeje, aki duro kato
kiwon nife ooni, aki bere kato kiwon nife ooye, KO
ga KO bere LA ki won nife ogbolu, tiwon ba ki won
ni Ife tan won ha ba bubu, ebo ni won fi iru won
se, ero Ife onilu kan obabatiriba, hun le omo onilu
kan obabatiribaa, omo onilukan ilukan to won fi
awo efan se ni ojosi ti won Wa fi aketenpe eti Erin
se osan re, omo fitila ketepe to n be lotu Ife lojosi,
Ina kiku ni be tosan toru, Ibe ni Baba Wa ti nka
owo eyo,

Ikan mesan ni wuyi ni Ife Baba wa

1. Iyan funfunn balahu kini ohun wuyi nife Baba Mi
2. kafa ori
apakan da apakan si kini ohun wuyi nife Baba Mi
3. Ikunle rugudu, kini ohun wuyi nife Baba Mi
4. Aso
funfun Nene owuyi nife Baba Mi
5. Sese efun owuyi
ni ife Baba Mi
6. Eepa osa owuyi nife Baba Mi
7. Oje owo tegitegi kini ohun wuyi nife Baba Mi
8. Obi pa, Obi fin owuyi ni Ife Baba Mi
9. Agogo enu, ori ti ki je
eku, ori ti kije eja, ori ti ki je ohunkohun afi omi
obe lore Kore, owuyi ni Ife Baba Mi.Omo obalufon ogbogbodinrin Tobi obalufon
alayemore, Iran Baba tiwa ni je OBALUFE Ati OONI
ni Ife ooye

Ojo ti eke eniwo Ku, agbe ile kan apata,
Ojo ti odale otoro Ku, agbe ile kan gbongbo,
Ojo ti
oloto otoro Ku, agbe ile akan apoti owo, apoti owo
wuyi, apoti owo rewa,

Gbogbo awa omo ODODA Nile olotoro, OLORUN KO ni pawa lekun
ooo. Amin, Asee, Esee.
Agboola gbenga

User avatar
ounpe
Reactions:
Posts: 37
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:16 am
Gender: None specified

Re: ORIKI AGBOOLE ODODA NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by ounpe » Fri Jan 13, 2017 12:50 pm

@Agboola gbenga, the oriki is a repetition. Delete the one below or @mayowa should do it for him.

User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Re: ORIKI AGBOOLE ODODA NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by Mayowa » Mon Jan 16, 2017 2:00 pm

ounpe wrote:@Agboola gbenga, the oriki is a repetition. Delete the one below or @mayowa should do it for him.
He has done that.
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

User avatar
ounpe
Reactions:
Posts: 37
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:16 am
Gender: None specified

Re: ORIKI AGBOOLE ODODA NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by ounpe » Wed Jan 18, 2017 2:47 pm

Mayowa wrote:
ounpe wrote:@Agboola gbenga, the oriki is a repetition. Delete the one below or @mayowa should do it for him.
He has done that.
OK :geek:

Agboola gbenga
Reactions:
Posts: 31
Joined: Thu Sep 08, 2016 9:51 am
Gender: Male

Re: ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON COMPOUND NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by Agboola gbenga » Sun Apr 02, 2017 2:23 pm

ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON
ORA-IGBOMINA

Awa lomo olotoro elere, omo elerin nla funfun, koto
ajija mekun lepe, keba Mi mekun lepe, keba Mi
mu ewure ibe, ewure otoro bami leru ju ekun ibe lo,
awa lomo jamo niya sonu, awa lomo jawe lemo lori, awa lomo ogoro nbe
nile e si aha, omo ogbon ni muni sahun nitori ba
meji ko, nitori awon wobia ni, omo asu olele
nigbati e si eree, awa lomo o gbo kuku ojo da omi agbada nu
lore, ojo setan e tun ro mo, gbogbo ayaba ile Wa lo
KO omo le itan, omo oniwo ku loyegbe kanran bi oko tuntun, ojo pa oniru iwo, ko se yan m. ojo pa oniyo iwo, iyo di okuta. ojo pa elekuru iwo, ko se yan mo. lope pekun, leti awoji, moriwo
Sara ogun ti iyemi kanle lepe, awa lomo Alaka
balagba, omo awobi sakaro Loko, awa lomo eniwo
ye yiwo, awa lomo ejemu yoo ni Ora, omo ejemu
abeki, omo ejemu owojemiosimi, awa lomo Ada
olufe, omo sajiku oro obalufon, Omo obalufe ni Ife ooye,Omo Seriki Ologun dudu, Omo a keru weeere soko, Omo a fun ni lowo nigba to Soro, Eerun ni o je ki n musu loke Ogba dele, Omo Aworo ti kii seke, Baba wa lo nile dajumonmu, Omo Koro Awo ajiki, Omo a lu koko soro, Omo ipako o gbo suti Ori elegan ni o fe pe, Iran baba wa kii je efo odu
Nitori iran omo aniwo, Omo omoomo Nana Ariyan mami nile a rapa fako, Akeyemo tun ni baba baba to bi o lomo. omo olodo kan otororooo, omo olodo kan
otararaaa, omo olodokan odo kan to san lo si eyinkule oshin to di abata, omo onife abure, omo amagbada owo remo, omo ooni erujeje, aki duro kato
kiwon nife ooni, aki bere kato kiwon nife ooye, KO
ga KO bere LA ki won nife ogbolu, tiwon ba ki won
ni Ife tan won ha ba bubu, ebo ni won fi iru won
se, ero Ife onilu kan obabatiriba, hun le omo onilu
kan obabatiribaa, omo onilukan ilukan to won fi
awo ekun se ni ojosi ti won Wa fi aketepe eti Erin
se osan re, omo fitila ketepe to n be lotu Ife lojosi,
Ina kiku ni be tosan toru, Ibe ni Baba Wa ti nka
owo eyo, ikan mesan ni wuyi ni Ife Baba Mi. iyan
funfun balahu kini ohun wuyi nife Baba Mi, kafa ori
apakan da apakan si kini ohun wuyi nife Baba Mi,
ikunle rugudu, kini ohun wuyi nife Baba Mi, aso
funfun Nene owuyi nife Baba Mi, sese efun owuyi
nife Baba Mi, eepa osa owuyi nife Baba Mi, oje
owo tegitegi kini ohun wuyi nife Baba Mi, obi pa
obi fin owuyi ni Ife Baba Mi, agogo enu, ori ti ki je
eku, ori ti kije eja, ori ti ki je ohunkohun afi omi
obe lore Kore, owuyi ni Ife Baba Mi, omo Ife odaye,
omo obalufon ogbogbodinrin Tobi obalufon
alayemore, Iran Baba tiwa ni je OBALUFE Ati OONI
ni Ife ooye, ojo ti eke eniwo Ku, agbe ile kan apata,
ojo ti odale otoro Ku, agbe ile kan gbongbo, ojo ti
oloto otoro Ku, agbe ile akan apoti owo, apoti owo
wuyi orewa, Gbogbo awa omo ODODA Nile olotoro,
OLORUN KO ni pawa lekun ooo. Amin, Asee.
ODODA Nile olotoro, OLORUN KO ni pawa lekun
ooo. Amin, Asee.

Agboola gbenga
Reactions:
Posts: 31
Joined: Thu Sep 08, 2016 9:51 am
Gender: Male

Re: ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON COMPOUND NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by Agboola gbenga » Sun Apr 02, 2017 2:24 pm

Agboola gbenga wrote:
Mon Jan 09, 2017 2:31 pm
ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON
ORA-IGBOMINA
Awa lomo olotoro elere, omo elerin nla funfun, koto
ajija mekun lepe, keba Mi mekun lepe, keba Mi
mu ewure ibe, ewure otoro bami leru ju ekun ibe lo,
awa lomo jamo niya sonu, awa lomo jawe lemo lori, awa lomo ogoro nbe
nile e si aha, omo ogbon ni muni sahun nitori ba
meji ko, nitori awon wobia ni, omo asu olele
nigbati e si eree, awa lomo o gbo kuku ojo da omi agbada nu
lore, ojo setan e tun ro mo, gbogbo ayaba ile Wa lo
KO omo le itan, lo pe pekun, leti awoji, moriwo
Sara ogun ti iyemi kanle lepe, awa lomo Alaka
balagba, omo awobi sakaro Loko, awa lomo eniwo
ye yiwo, awa lomo ejemu yoo ni Ora, omo ejemu
abeki, omo ejemu owojemiosimi, awa lomo Ada
olufe, omo sajiku oro obalufon, Omo obalufe ni Ife ooye, Omo ogun enire,
omo olodo kan otororooo, omo olodo kan
otararaaa, omo olodokan odo kan to san lo si eyinkule oshin to di abata, omo onife abure, omo amagbada owo remo, omo ooni erujeje, aki duro kato
kiwon nife ooni, aki bere kato kiwon nife ooye, KO
ga KO bere LA ki won nife ogbolu, tiwon ba ki won
ni Ife tan won ha ba bubu, ebo ni won fi iru won
se, ero Ife onilu kan obabatiriba, hun le omo onilu
kan obabatiribaa, omo onilukan ilukan to won fi
awo ekun se ni ojosi ti won Wa fi aketepe eti Erin
se osan re, omo fitila ketepe to n be lotu Ife lojosi,
Ina kiku ni be tosan toru, Ibe ni Baba Wa ti nka
owo eyo, ikan mesan ni wuyi ni Ife Baba Mi. iyan
funfun balahu kini ohun wuyi nife Baba Mi, kafa ori
apakan da apakan si kini ohun wuyi nife Baba Mi,
ikunle rugudu, kini ohun wuyi nife Baba Mi, aso
funfun Nene owuyi nife Baba Mi, sese efun owuyi
nife Baba Mi, eepa osa owuyi nife Baba Mi, oje
owo tegitegi kini ohun wuyi nife Baba Mi, obi pa
obi fin owuyi ni Ife Baba Mi, agogo enu, ori ti ki je
eku, ori ti kije eja, ori ti ki je ohunkohun afi omi
obe lore Kore, owuyi ni Ife Baba Mi, omo Ife odaye,
omo obalufon ogbogbodinrin Tobi obalufon
alayemore, Iran Baba tiwa ni je OBALUFE Ati OONI
ni Ife ooye, ojo ti eke eniwo Ku, agbe ile kan apata,
ojo ti odale otoro Ku, agbe ile kan gbongbo, ojo ti
oloto otoro Ku, agbe ile akan apoti owo, apoti owo
wuyi orewa, Gbogbo awa omo ODODA Nile olotoro,
OLORUN KO ni pawa lekun ooo. Amin, Asee.
ODODA Nile olotoro, OLORUN KO ni pawa lekun
ooo. Amin, Asee.

Agboola gbenga
Reactions:
Posts: 31
Joined: Thu Sep 08, 2016 9:51 am
Gender: Male

Re: ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON COMPOUND NI ILU ORA-IGBOMINA

Post by Agboola gbenga » Sun Apr 02, 2017 2:26 pm

ORIKI AGBO'LE ODODA OBALUFON
ORA-IGBOMINA

Awa lomo olotoro elere, omo elerin nla funfun, koto
ajija mekun lepe, keba Mi mekun lepe, keba Mi
mu ewure ibe, ewure otoro bami leru ju ekun ibe lo,
awa lomo jamo niya sonu, awa lomo jawe lemo lori, awa lomo ogoro nbe
nile e si aha, omo ogbon ni muni sahun nitori ba
meji ko, nitori awon wobia ni, omo asu olele
nigbati e si eree, awa lomo o gbo kuku ojo da omi agbada nu
lore, ojo setan e tun ro mo, gbogbo ayaba ile Wa lo
KO omo le itan, lo pe pekun, leti awoji, moriwo
Sara ogun ti iyemi kanle lepe, awa lomo Alaka
balagba, omo awobi sakaro Loko, awa lomo eniwo
ye yiwo, awa lomo ejemu yoo ni Ora, omo ejemu
abeki, omo ejemu owojemiosimi, awa lomo Ada
olufe, omo sajiku oro obalufon, Omo obalufe ni Ife ooye,Omo Seriki Ologun dudu, Omo a keru weeere soko, Omo a fun ni lowo nigba to Soro, Eerun ni o je ki n musu loke Ogba dele, Omo Aworo ti kii seke, Baba wa lo nile dajumonmu, Omo Koro Awo ajiki, Omo a lu koko soro, Omo ipako o gbo suti Ori elegan ni o fe pe, Iran baba wa kii je efo odu
Nitori iran omo aniwo, Omo omoomo Nana Ariyan mami nile a rapa fako, Akeyemo tun ni baba baba to bi o lomo. omo olodo kan otororooo, omo olodo kan
otararaaa, omo olodokan odo kan to san lo si eyinkule oshin to di abata, omo onife abure, omo amagbada owo remo, omo ooni erujeje, aki duro kato
kiwon nife ooni, aki bere kato kiwon nife ooye, KO
ga KO bere LA ki won nife ogbolu, tiwon ba ki won
ni Ife tan won ha ba bubu, ebo ni won fi iru won
se, ero Ife onilu kan obabatiriba, hun le omo onilu
kan obabatiribaa, omo onilukan ilukan to won fi
awo ekun se ni ojosi ti won Wa fi aketepe eti Erin
se osan re, omo fitila ketepe to n be lotu Ife lojosi,
Ina kiku ni be tosan toru, Ibe ni Baba Wa ti nka
owo eyo, ikan mesan ni wuyi ni Ife Baba Mi. iyan
funfun balahu kini ohun wuyi nife Baba Mi, kafa ori
apakan da apakan si kini ohun wuyi nife Baba Mi,
ikunle rugudu, kini ohun wuyi nife Baba Mi, aso
funfun Nene owuyi nife Baba Mi, sese efun owuyi
nife Baba Mi, eepa osa owuyi nife Baba Mi, oje
owo tegitegi kini ohun wuyi nife Baba Mi, obi pa
obi fin owuyi ni Ife Baba Mi, agogo enu, ori ti ki je
eku, ori ti kije eja, ori ti ki je ohunkohun afi omi
obe lore Kore, owuyi ni Ife Baba Mi, omo Ife odaye,
omo obalufon ogbogbodinrin Tobi obalufon
alayemore, Iran Baba tiwa ni je OBALUFE Ati OONI
ni Ife ooye, ojo ti eke eniwo Ku, agbe ile kan apata,
ojo ti odale otoro Ku, agbe ile kan gbongbo, ojo ti
oloto otoro Ku, agbe ile akan apoti owo, apoti owo
wuyi orewa, Gbogbo awa omo ODODA Nile olotoro,
OLORUN KO ni pawa lekun ooo. Amin, Asee.
ODODA Nile olotoro, OLORUN KO ni pawa lekun
ooo. Amin, Asee.

Post Reply
  • Similar Topics
    Replies
    Views
    Last post

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 3 guests