A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

HOW TO MAKE IT POWERFULLY IN YEAR 2017

Post Reply
sofunbej
Reactions:
Posts: 16
Joined: Thu Nov 10, 2016 11:29 am
Gender: Male

HOW TO MAKE IT POWERFULLY IN YEAR 2017

Post by sofunbej » Thu Jan 12, 2017 12:34 am

Everybody likes success, but it does not come cheaply. It requires conscious preparation. Therefore, as you proceed in the new year you can lay the foundation of good success by focusing on the following seven areas:

1. Divine Presence. You must desire the presence of God wherever you go this year. His presence will guarantee you sweatless favour.
(Psalm 34:7).

2. Divine Power. You need to pray for the power of God so that wherever you are, you can experience God’s power working for you. This will crown your efforts with cheap results.

3. Divine Protection. You need to pray for divine protection of the Almighty God, so that the enemy will not terminate your life prematurely. The world is full of evil, and when you secure yourself in the secret place of God you are safe. (Psalm 91:1-16). This implies that you must be His son (John 1:12). If you are not saved, you are not safe.

4. Divine Provision. You need to pray for divine provision for your needs as you proceed in the year. The cheapest way to get this is to be interested and committed to anything that pertains to God e.g. God’s work, God’s people, etc. Jesus Christ revealed the secret when he said, ‘Seek ye first the kingdom of God, and his righteousness,; and all these things shall be added unto you.’ (Matthew 6:33).

5. Divine Purpose. You need to pray to know and fulfill your divine purpose. Always ask, ‘what is the purpose of my existence’ how can I achieve it. What am I living for? How can I impact others positively. Have a long time goal to impact humanity, a goal that you will be remembered for when you are no longer around. Don’t live for the now alone.

6. Diving Positioning: Pray for divine positioning because 99 per cent of success depends on divine positioning. That God will make you to be at the right location so that you can get your allocation.

7. Divine Promotion: You need to pray for God’s promotion. God’s promotion is enduring, and is without sweat. With God’s promotion, you will be singled out among others for elevation and advancement. This is the year of our glory!

PRAYER POINTS
Read Psalm 103.

1. Lord, I thank you for the gift of life and everything you have done for me.
2. As I proceed in the year 2017 let your presence go with me.
3. Empower me to live in obedience to your word.
4. As you feed the ants on the ground, and the birds in the air, connect me to divine provision this year in Jesus name.
5. O Lord, let me live to fulfil your purpose for my life. I shall not disappoint you in Jesus name.
6. My Father, position me strategically to my place of blessing this year in Jesus name.
7. Thank God for the answered prayers. =====================


BI O TI SE LÈ RỌWỌ MU NINU ODUN 2017
Gbogbo eniyan lo feran aseyori, sugbon aseyori ko le wa laisepe eniyan sise fun. O nilati murasile. Nitorina bi o se nlo ninu odun tuntun, fi ipile aseyori re le’lẹ nipase awon ifojusun meje wonyi:

1. Iwa Laaye Olorun. O gbodo pòngbẹ iwalaaye Olorun nibikibi ti o ba lo lodun yi. Iwalaaye Re yio fun o ni ojurere lailaagun. (Orin Dafidi 34:7).

2. Agbara Olorun. O ni lati gbadura fun agbara Olorun, to je wipe ibikibi ti o ba wa, wà á ni iriri agbara Olorun to nsise fun o. Eyi yio fi èrè sori ise re lopolopo.

3. Aabo Olorun. O gbodo gbadura fun aabo Olorun, ki ota ma baa da ẹmi re légbodò. Aye kun fun ibi, sugbon nigbati o ba fi ara re saabo ibi nibi ikọkọ Olorun o ó wa lailewu. (Orin Dafidi 91:1-16). Eyi tumo si wipe o gbodo je omo Olorun (John 1:12), laise bẹẹ, o wa ninu ewu.

4. Ipese Olorun. O gbodo gbadura fun ipese Olorun fun gbogbo aini re ninu odun yi. Ọna tó ya julo lati ri eyi ni ti o ba nife si ohunkohun tii se ti Olorun. Fun apeere , sise atilehin fun ise Olorun, ati awon eniyan Olorun. Jesu Kristi fi asiri na han gbangba nigba to so wipe ‘E tete wa ijoba Olorun na ati ododo re; awon ohun to ku a o fikun fun yin.’ (Matiu 6:33).

5. Ilepa lat’odo Olorun. Gbadura fun ilepa latorun wa. Nigbagbogbo maa bi ara re léèrè, ‘kini’di ti mo fi wa saye. Bawo ni mo sele mu se? bawo ni mo sele ran awon miran lowo? Ni ilepa fun ojo iwaju, paapaa julo kini ohun ti awon eniyan yio ranti re si nigbati o ba lo. Mase gbe igbe aye jeun-k'o-o-ku.

6. Fifini sipo lat’orun wa. Gbadura ki Olorun fi e si ipo nitoripe gbogbo aseyori lo fee duro lori fifi sipo lat’orun wa. Gbadura ki Olorun fi o sipo to pé’ye ki o le raye gba eto re.

7. Igbega lat’odo Olorun. O ni lati gbadura fun igbega Olorun. (Orin Dafidi 75:6) Igbega Olorun maa nbani kalẹ, ko si ni wahala. Pelu igbega Olorun, a o fa o yo laarin awon miran fun igbega ati itesiwaju.


AWON KOKO ADURA
Ka Orin Dafidi 103.

1. Oluwa, mo dupe fun ebun wipe mo wa laaye, ati fun gbogbo ohun to o se fun mi.
2. Bi mo ti n lo ninu odun 2017 jeki iwalaaye re wa pelu mi.
3. Fi agbara kun mi ki ngbe igbesi aye mi pelu igboran si oro Re.
4. Bi o ti n fun eera ile lounje, ati eye oju orun, so mi po mo ipese latorun wa l’odun yi ni oruko Jesu.
5. Oluwa, jeki igbesi aye mi mu ipinnu Re se fun mi laye. Nko ni ja O kule ni oruko Jesu.
6. Baba mi, fi mi sipo ibukun mi l’odun yi ni oruko Jesu.
7. Dupe lowo Olorun fun idahun adura yi.
Attachments
Divine promotion.jpg
Igbega lat'odo Olorun
divine purpose.jpg
Divine Purpose
divine purpose.jpg (12.37 KiB) Viewed 820 times

Post Reply
  • Similar Topics
    Replies
    Views
    Last post

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 1 guest