A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

What Next?

Post Reply
sofunbej
Reactions:
Posts: 16
Joined: Thu Nov 10, 2016 11:29 am
Gender: Male

What Next?

Post by sofunbej » Sun Dec 18, 2016 11:03 pm

Last time, we talked briefly on what Christianity is, and those things that Christians believe. We also saw the need for everyone to give his/her life to Jesus Christ as Lord and Saviour.

If you did, Congratulations! You have made a life-changing decision! Perhaps you are asking, “Now what next? How do I begin my journey with God?” The following five steps will give you direction from the Bible.

1. Make sure you understand salvation.

Briefly, let’s go over the key points of salvation:

(a) We have all sinned. We have all done things that are displeasing to God (Romans 3:23).

(b) Because of our sin, we deserve to be punished with eternal separation from God (Romans 6:23).

(c) Jesus died on the cross to pay the penalty for our sins (Romans 5:8; 2 Corinthians 5:21). Jesus’ resurrection proved that His death was sufficient to pay for our sins.

(d) God grants forgiveness and salvation to all those who place their faith in Jesus Christ —trusting His death as the payment for our sins (John 3:16; Romans 8:1).

(e) The Holy Spirit comes to live in us the moment we receive Jesus Christ as our Lord and Saviour. He assures us of everlasting life, teaches us God’s Word and empowers us to live accordingly.

Therefore, if you have placed your faith in Jesus Christ as your Savior, you can have confidence that you will spend eternity with God in heaven! (John 10:28-29).

2. Find a church that teaches and practises the Bible.

Now that you have placed your faith in Jesus Christ, you should find, and begin to attend a Bible-believing church in your area. Speak to the pastor, and let him know about your new faith in Jesus Christ.

The church will teach you more about the Bible, and how you can apply God’s instructions to your life. This will help you to live a powerful Christian life.

3. Set aside time each day for devotion.

It is very important to spend time each day with God in prayer. This is called a “quiet time” or “devotion”. You may choose a convenient time for this either early in the morning or late in the evening. Make it a habit to do this regularly. Two things to do during this period are:

(a) Prayer. Pray about your concerns and challenges. Ask God to provide for your needs, and to give you wisdom and guidance. Tell God how much you love Him and how much you appreciate all He does for you.

(b) Bible Study. You need to study the Bible for yourself. The Bible is God’s Word to us. It is His manual to guide us in making wise decisions, and to live our lives in a way that is pleasing to Him. (II Timothy 3:6).

4. Develop relationships with people who can help you spiritually.
Surround yourself with people who love God and are committed to Him. Find a friend or two, perhaps from your church, who can help you and encourage you to grow spiritually, especially in regard to your quiet time, your activities, and your walk with God.

This does not mean you have to give up all your other friends who do not know the Lord Jesus as their Savior. Simply let them know that Jesus has changed your life and you cannot do again all the sinful things you used to do. Ask God to give you opportunities to share Jesus with your friends.

5. Be baptized.
Baptism is important because it is a step of obedience. It is a biblical way to publicly proclaim your new faith in Christ and your decision to follow Him.

The action of being immersed in the water illustrates being buried with Christ;
While the action of coming out of the water pictures Christ’s resurrection. Being baptized is identifying yourself with Jesus’ death, burial, and resurrection (Romans 6:3-4).
You should speak with your Pastor who will guide you through this process.

6. Serve God
You have been saved to serve. Therefore, prayerfully consider whatever activity you can do in the church where you are, based on your ability, inorder to promote the work of God. As you do this you will experience the blessing of God upon every area of your life. You can also talk to your Pastor who will guide you accordingly.

If you have questions on any of these issues, please feel free to ask.

END-OF-YEAR PRAYERS
Meanwhile, pray the following prayers powerfully.

• Praise and worship God for making you to see the morning (January), and the night (December) of year 2016 (Psalm 92:1-2).
• Lord, I thank you because of your investment in my life.
• O Lord, establish me in you, and plant good things in my life in the name of Jesus.
• O Lord, as this year is coming to an end, baptise me with ‘Come and see’ miracle in the name of Jesus.
• My Father, deliver me from end of the year tragedy, in the name of Jesus.
• O Lord, however cheap the price of coffin may be, people shall not present it to me as a gift in the name of Jesus.
• O God reorganise my life to deepen my love for you in the name of Jesus.
• Thank God for the answered prayers.


=======================

[/b][/b]Kiló Kàn?

Ninu ijiroro wa kehin, a soro lori ohun ti kristeni je, ati kini ohun ti awon kristeni gbagbọ. A si rii daju idi pataki ti o ni lati fi aye re fun Jesu Kristi gegebi Oluwa ati Olugbala re

Ti o ba se eyi, mo ki o ku ori’re! O ti se ipinnu ti yio yi aye re pada si rere! Nisisiyi, o le maa bere wipe, “Kiló kàn? Bawo ni mo se fe bere irin ajo mi pelu Olorun?” Awon ipese marun wonyi yio fun o ni itoni latinu Bibeli.


1. Rii daju pe o ni oye igbala.

Ni kukuru, jeki a se agbeyewo koko oro nipa igbala:

(a) Gbogbo wa lo ti sẹ. A ti se awon ohun ti ko mu inu Olorun dun. (Romu 3:23).

(b) Nitori ese wa, a ye fun iyapa ayeraye kuro lodo Olorun (Romu 6:23).

(c) Jesu ku lori agbelebu lati san igbese fun ese wa (Romu 5:8; 2 Korinti 5:21). Jesus je iya to to siwa. Ajinde Jesu fihan wipe iku Re to lati san’gbese ese wa.

(d) Olorun fi idariji ati igbala fun gbogbo awon to fi igbagbo won sinu Jesu Kristi (Johanu 3:16; Romans 8:1).

(e) Emi Mimo wa lati gbe inu wa ni kete ti a gba Jesu Kristi gegebi Oluwa ati Olugbala wa. O fun wa nidaniloju iye ainipekun, O nkowa ni Oro Olorun, O si nfunwa lagbara lati gbe igbe aye wa lati igba na lo.

Nitorina, ti o ba ti fi igbagbo re sinu Jesu Kristi gegebi Olugbala re, o le ni igbekele wipe iwo yio wa ni iye ayeraye pelu Olorun. (John 10:28-29).

2. Darapo mo ijo ti o nko Bibeli , to si nhuwa bee.

Nisisiyi ti o fi igbagbo re sinu Jesu Kristi, o gbodo wa ijo Olorun nibiti o ti le ko eko Bibeli ni agbegbe re, ki o si ma lo sibe. So fun olusoagutan ijo na, ki o si jeki o mo nipa igbagbo re ninu Jesu Kristi.

Ijo na yio ko o ni imo Bibeli, ati bi o se le mu itoni Olorun lo si igbesi aye re. Eyi yio ran o lowo lati gbe igbe aye onigbagbo to laseyori.

3. Ya akoko soto fun ijosin lojoojumo.

O se Pataki lati lo akoko pelu Olorun lojoojumo ninu adura. A npe eleyi ni ’akoko idake jee’ tabi íjosin’. O le yan akoko to wu o boya ni kutukutu laaaro tabi ni ale patapata. So di asa lati maa se eyi nigbagbogbo. Ohun meji ti o ni lati se lakoko yi ni:

(a) Adura. Gbadura lori awon ohun to je edun okan re. So fun Olorun lati pese fun awon aini re, ati ogbon ati itoni. So Olorun bi o ti feran Re to, ati bi o se mo riri ohun ti O nse fun o.

(b) Kika Bibeli. O nilo lati maa ka Bibeli funraa re. The Bible is God’s Word to us. O je iwe atoka lati to wa si ilana ogbon, ati bi a se le gbe igbesi aye wa lona ti yoo wuu. (II Timotiu 3:6).

4. Ni ibasepọ pelu awon to le ran o lowo ni ti ẹmi.
Wa laaarin awon eniyan to feran Olorun ti won si farawon jin fun Olorun.

Gbiyanju lati wa ore kan tabi meji, boya latinu ijo re, to le ran o lowo. So fun awon ore re lati maa to o sona ninu ohun to jemo wakati idakeroro, iwa ati ise re, ati irin re pelu Olorun.

Eyi ko tumo si wipe ki o ko awon ore re ti ko mo Jesu Kristi gegebi Oluwa ati Olugbala. Sugbon jeki won mo wipe Jesu ti yi aye re pada, o ko si le maa huwa ese ti e jo maa nhu tele. Gbadura ki Olorun fun o ni aaye lati soro nipa Jesu fun awon ore re.

5. Se iribomi.
Iribomi se Pataki nitoripe o je igbésẹ igbọran. Ohun ni ona bibeli lati se afihan gbangba igbagbo re tuntun ninu Jesu ati ipinnu re lati tele E. Sise iribomi ninu omi se apejuwe sisin pelu Kristi.
Jijade kuro ninu omi nse afihan aworan ajinde Kristi.

Sise iribomi je fifi ara re han pelu iku Jesu, sisin, ati ajinde Re. (Romu 6:3-4).
Lo sodo olusoagutan re, lati ran o lowo lati se iribomi na nigbati o ba setan.

6. Sin Olorun
A ti gba o la ki o le sin Olorun. Nitorina, pelu adura ronu lori ise ti o le maa se gegebi o ti ni oore-ofe si ninu ijo ti o ba nlo, lati se atilehin fun ise Olorun. Bi o ti n se eyi, wa a ri ibukun Olorun nigbogbo ona lori aye re. O le ba olusoagutan re jiroro nipa eyi, won a si gba o nimoran siwaju si.

Ti o ba ni ibeere lori awon nkan wonyi, mase tiju, beere.


ADURA ODUN
Gba awon adura yi pelu gbogbo agbara rẹ

• Yin Olorun ti o mu o ri aaro (Osu kini), ati alẹ (Osu kejila) odun 2016 (Orin Dafidi 92:1-2).
• Oluwa, Mo dupe lowo Re fun awon idokowo Re ninu aye mi.
• My Father, fi ese mi mule ninu Re, ki nmaa se ife re nigbagbogbo ni oruko Jesu.
• Oluwa, gbin ohun rere sinu aye mi ni oruko Jesu.
• Oluwa, bi odun yi tin lo sopin, fi iribọmi isẹ iyanu, ‘Wa woo’ damilọlá, ni oruko Jesu.
• Baba mi, gba mi lowo gbogbo awon ijamba opin odun, ni oruko Jesu.
• Oluwa, boti wu ki owo posi dinku to, aye ko ni fi tamilọrẹ, ni oruko Jesu.
• Olorun o, tun aye mi to ki njinlẹ ninu ife Re ni oruko Jesu.
• Dupe lowo Olorun fun idahun adura yi.
Attachments
Heaven.jpg
Ayeraye pelu Olorun
Heaven.jpg (4.73 KiB) Viewed 471 times
bible study.1jpg.jpg
Bible Study
bible study.1jpg.jpg (7.17 KiB) Viewed 471 times
baptism 5.jpg
Baptism
baptism 5.jpg (7.61 KiB) Viewed 471 times
Prayer.3jpg.jpg
Adura Gbigba
Prayer.3jpg.jpg (5.28 KiB) Viewed 471 times
baptism 2.jpg
Iribomi
baptism 2.jpg (8.5 KiB) Viewed 471 times

Post Reply

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 1 guest