A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post Reply
User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Tue Apr 04, 2017 4:37 pm

Mo tun gbe titun de o. Awọn awọ ni ede Yoruba ni mo gbe de loni. Awọn awọ ti emi mọ ni awọn wọnyi amọ ti ẹnikẹni ba ni tabi mọ ju bẹ lọ, ẹ le ṣe afikun oun ti mo kọ, ẹ ṣe pupọ.

1. Awọ Dudu - Black colour
black-awo dudu.jpg
Black colour - Awọ dudu ni Yoruba
black-awo dudu.jpg (2.18 KiB) Viewed 2021 times

2. Awọ funfun
white-funfun.jpg
White colour - Awọ funfun ni Yoruba
white-funfun.jpg (1.53 KiB) Viewed 2017 times


User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Tue Apr 04, 2017 4:42 pm

3. Awọ Pupa - Red colour
red-awo pupa.jpg
red-awo pupa.jpg (3.68 KiB) Viewed 2020 times

4. Awọ Aluko - Purple colour
purple-awo aluko.jpg
purple-awo aluko.jpg (2.16 KiB) Viewed 2011 times


User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Tue Apr 04, 2017 4:46 pm

5. Awọ Ọsan - Orange colour
orange-awo osan.jpg
orange-awo osan ni Yoruba
orange-awo osan.jpg (2.04 KiB) Viewed 2020 times

6. Awọ Obedo - Green colour
green-awo obedo.jpg
green-awo obedo ni Yoruba
green-awo obedo.jpg (2.17 KiB) Viewed 2020 times


User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Wed Apr 05, 2017 12:39 pm

7. Awọ ọlọyẹ - Gray colour
awo oloye-gray.jpg
awo oloye-gray.jpg (2.04 KiB) Viewed 2015 times

8. Awọ Waji - Blue colour
blue - Awo waji.jpg
blue - Awo waji.jpg (1.76 KiB) Viewed 2015 times


User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Wed Apr 05, 2017 12:50 pm

9. Awọ pipọn - Yellow colour
yellow-awo pipon.jpg
yellow-awo pipon.jpg (2 KiB) Viewed 2014 times

10. Awọ Sanmọ - Sky blue colour
sky blue-awo sanmo.jpg
sky blue-awo sanmo.jpg (2.2 KiB) Viewed 2014 times


User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Wed Apr 05, 2017 1:32 pm

11. Awọ Ayinrin - Light blue
light blue-awo ayinrin.jpg
light blue-awo ayinrin.jpg (2.78 KiB) Viewed 2013 times

12. Awọ Orombo - Lemon
awo orombo - lemon.jpg
awo orombo - lemon.jpg (1.89 KiB) Viewed 2013 times

13. Awọ rẹsurẹsu - Brown
Brown - awo rusurusu.jpg
Brown - awo rusurusu.jpg (2.1 KiB) Viewed 2013 times


User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by orisun » Wed Apr 05, 2017 4:36 pm

14. Awọ Aro - Indigo colour
Awo Aro - Indigo.jpg
Awo Aro - Indigo.jpg (1.75 KiB) Viewed 2009 times

User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Re: Awo ni Yoruba / Colours in Yoruba Language

Post by Mayowa » Mon Apr 10, 2017 10:13 am

Green can be called Awo ewe too and brown can be called awa ara.
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

Post Reply
  • Similar Topics
    Replies
    Views
    Last post

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 8 guests